Òrúnmílá loloni
Ifá lolola
Òrúnmìlà lolotunla pelu
Ifá loni ojo merin osadakile aye
Adifafun ojose
tinse omo bibi inu Agboniregun
ebo won ni ose
Ogbebo nigbe orugbo
Ifá toba semi ti mobafilaje
Noman peloni lojo osetemi
Òrúnmìlà oni lojose
Ifá toba semi timo ba fini
Ire bogbo
Noman pelonio lojo osetemi
Òrúnmìlà oni lojose.
Ifá toba semi ti mobafilaje
noman peloni lojo osetemi
Orunmila oni lojose
ifá toba semi timo ba fini
iré gbogbo
no man pelini olojose temi
Orunmila oni lojose, etc.
Traducción: